ẹyọ
See also: -eyo
Yoruba
Alternative forms
Etymology
Compare with Igala ẹ́yọ́ (“one seed”)
Pronunciation
- IPA(key): /ɛ̄.jɔ̄/
Noun
ẹyọ
- one item, one unit
- Mú ẹyọ kan nínú àwọn ìwé yẹn wá ― Bring one of those books here
- single, singular, singularity
Derived terms
- owó ẹyọ (“one cowry, coin”)
- ẹyọ owó
- ẹyẹẹyọ (“in singles”)