ọwọ ọtun
Yoruba
Etymology
From ọwọ́ (“hand”) + ọ̀tún (“right”).
Pronunciation
- IPA(key): /ɔ̄.wɔ́ ɔ̀.tṹ/
Noun
ọwọ́ ọ̀tún
- right-hand; right side
- Synonym: apá ọ̀tún
- Antonyms: ọwọ́ òsì, apá òsì, (euphemistic) ọwọ́ àlàáfíà
Derived terms
- lọ́wọ́ ọ̀tún
- ọlọ́wọ́ ọ̀tún (“right handed person”)