Yoruba
Etymology
Compare with Itsekiri agura (“star”)
Pronunciation
Proper noun
Àgùàlà
- (astronomy) Venus; the second planet in the solar system. Symbol: ♀.
- Synonym: ajá òṣùpá
- Àgùàlà ń bá òṣùpá rìn, wọ́n ní ajá ẹ̀ ló ń ṣe. ― Venus and the moon can often be sighted together. (literally, “Venus walks with the moon, they say it's being its dog.”)