Yoruba
Etymology
Possibly cognate with Fon agbadé, Gun gbàdó, Igbo ọ̀gbàdụ
Pronunciation
Noun
àgbàdo
- maize, corn
- Synonyms: ọkà, yangan, eginrin, eginrin àgbàdo, ẹlẹ́pà, ìjẹ́rẹ́
- Bí agbada ò bá gbóná, àgbàdo ò lè ta ― If the pan isn't hot, the corn won't pop
Derived terms
- háhá àgbàdo (“corn husk”)
- igi àgbàdo (“corn stalk”)
- ìrùkẹ̀rẹ̀ àgbàdo (“corn silk”)
Descendants