fẹran
Yoruba
Alternative forms
فعَِرَن
Etymology
From
fẹ́
(
“
to like
”
)
+
ràn
Pronunciation
IPA
(
key
)
:
/fɛ́.ɾã̀/
Verb
fẹ́ràn
to
like
; to
love
or be
fond
of someone or something
Synonym:
fẹ́
Ó
fẹ́ràn
láti máa lọ sí ilé-ìwé láràárọ̀
―
She
likes
to go to school every morning
Derived terms
ìfẹ́ràn
(
“
love
”
)