imọ iṣiro

Yoruba

Etymology

From ìmọ̀ (knowledge) +‎ ìṣirò (mathematics).

Pronunciation

  • IPA(key): /ì.mɔ̃̀ ì.ʃī.ɾò/

Noun

ìmọ̀ ìṣirò

  1. mathematics, arithmetic

Derived terms

  • onímọ̀ ìṣirò (mathematician)