imọ ijinlẹ
Yoruba
Etymology
From ìmọ̀ + ìjìnlẹ̀, literally “deep or profound knowledge”.
Pronunciation
- IPA(key): /ì.mɔ̃̀ ì.d͡ʒĩ̀.lɛ̀/
Noun
Derived terms
- onímọ̀ ìjìnlẹ̀ (“scientist”)
- ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ ẹ̀dá-èdè (“linguistics”)
- ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ sáyẹ́ǹsì ẹranko (“zoology, animal biology”)
- ìmọ̀ ìjìnlẹ̀-èrò (“philosophy”)
- ìmọ̀ ìjìnlẹ̀-èrò adálérí-ìgbádùn (“hedonism”)
- ìmọ̀ ìjìnlẹ̀-èrò ajẹmọ́-wíwà (“metaphysics”)