omiro
Yoruba
Etymology
From omi (“water”) + oró (“toxin, poison”)
Pronunciation
- IPA(key): /ō.mĩ̄.ɾó/
Noun
omiró
- salt water
- Synonym: omi-iyọ̀
- (chemistry) acid
Derived terms
- ìfa-omiró-nǹkanyọ (“distillation”)
- omiró fọ́sífọ̀ (“phosphoric acid”)
- omiró àtìgbàdégbà (“periodic acid”)